Contact Us

Spread the love

 Ìnlééo Omo Oníjèbú Ègbòrò

This is another selfless effort by sons and daughters of ÌJÈBÚ-JÈSÀ as their contributions towards the development of our community. Welcome to the Information highway. 
 
Hin pele o o o gbogbo egboro, omo awure fase banu. Oni a san a o. A ma ri idaamu. Wahala o kere o tobi maa je tia. Ojumo ayo lo mo fun a loni. Ju gbogbo re lo a ni jade leku lowo. Have a blissful weekend. 
 
Ègbòrò a gbe wa o.